Àwọn Ọba Kinni 13:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu ibojì tirẹ̀ gan-an ni ó sin ín sí. Òun ati àwọn ọmọ rẹ̀ sì ṣọ̀fọ̀ rẹ̀, ó ní, “Ó ṣe, arakunrin mi! Arakunrin mi!”

Àwọn Ọba Kinni 13

Àwọn Ọba Kinni 13:26-34