Àwọn Ọba Kinni 13:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Wolii àgbàlagbà yìí gbé òkú ọkunrin náà sí ẹ̀yìn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ̀ ó sì gbé e pada wá sí ìlú Bẹtẹli láti ṣọ̀fọ̀ rẹ̀, ati láti sin ín.

Àwọn Ọba Kinni 13

Àwọn Ọba Kinni 13:19-34