Àwọn Ọba Kinni 13:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Wolii àgbàlagbà náà bá bi wọ́n pé, “Ọ̀nà ibo ni ó gbà lọ?” Wọ́n sì fi ọ̀nà náà hàn án.

Àwọn Ọba Kinni 13

Àwọn Ọba Kinni 13:8-22