Àwọn Ọba Kinni 13:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Wolii àgbàlagbà kan wà ní ìlú Bẹtẹli ní ìgbà náà. Àwọn ọmọ wolii náà lọ sọ ohun tí wolii tí ó wá láti Juda ṣe ní Bẹtẹli ní ọjọ́ náà fún baba wọn, ati ohun tí ó sọ fún Jeroboamu ọba.

Àwọn Ọba Kinni 13

Àwọn Ọba Kinni 13:8-19