Àwọn Ọba Kinni 13:1 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA pàṣẹ fún wolii kan, ará Juda, pé kí ó lọ sí Bẹtẹli; nígbà tí ó débẹ̀ ó bá Jeroboamu tí ó dúró níwájú pẹpẹ láti sun turari.

Àwọn Ọba Kinni 13

Àwọn Ọba Kinni 13:1-10