Àwọn Ọba Kinni 12:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kẹẹdogun oṣù kẹjọ tíí ṣe ọjọ́ tí ó yàn fún ara rẹ̀, ó lọ sí ibi pẹpẹ tí ó kọ́ sí ìlú Bẹtẹli láti rúbọ. Ó yan àjọ̀dún fún àwọn ọmọ Israẹli, ó sì lọ sun turari lórí pẹpẹ.

Àwọn Ọba Kinni 12

Àwọn Ọba Kinni 12:28-33