Àwọn Ọba Kinni 12:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bi wọ́n léèrè, ó ní, “Kí ni ìmọ̀ràn tí ẹ lè gbà mí, lórí irú ìdáhùn tí a le fún àwọn eniyan tí wọ́n ní kí n dín ẹrù wúwo tí baba mi dì lé àwọn lórí kù?”

Àwọn Ọba Kinni 12

Àwọn Ọba Kinni 12:8-16