Àwọn Ọba Kinni 12:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ó kọ ìmọ̀ràn tí àwọn àgbààgbà fún un. Kàkà bẹ́ẹ̀, ó jíròrò pẹlu àwọn ọdọmọkunrin, ẹlẹgbẹ́ rẹ̀, tí wọ́n jọ dàgbà pọ̀, tí wọ́n wà ní ààfin pẹlu rẹ̀.

Àwọn Ọba Kinni 12

Àwọn Ọba Kinni 12:7-12