Àwọn Ọba Kinni 12:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ọba kò gbọ́ ti àwọn eniyan náà, nítorí pé OLUWA alára ni ó fẹ́ kí ọ̀rọ̀ yìí rí bẹ́ẹ̀, kí ọ̀rọ̀ OLUWA lè ṣẹ, tí ó bá Jeroboamu ọmọ Nebati sọ, láti ẹnu wolii Ahija ará Ṣilo.

Àwọn Ọba Kinni 12

Àwọn Ọba Kinni 12:11-16