Àwọn Ọba Kinni 12:14 BIBELI MIMỌ (BM)

gẹ́gẹ́ bí àwọn ọdọmọkunrin ti gbà á nímọ̀ràn. Ó ní, “Ẹrù wúwo ni ẹ sọ pé baba mi dì rù yín, ṣugbọn èmi yóo tilẹ̀ tún dì kún un ni. Ẹgba ni ó fi nà yín, ṣugbọn àkeekèé ni n óo máa fi ta yín.”

Àwọn Ọba Kinni 12

Àwọn Ọba Kinni 12:13-24