Àwọn Ọba Kinni 11:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Inú bí OLUWA sí Solomoni, nítorí pé, ọkàn rẹ̀ ti yipada kúrò lọ́dọ̀ OLUWA Ọlọrun Israẹli tí ó fara hàn án nígbà meji,

Àwọn Ọba Kinni 11

Àwọn Ọba Kinni 11:1-15