Àwọn Ọba Kinni 11:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni ó ṣe fún gbogbo àwọn iyawo àjèjì tí ó fẹ́, tí wọn ń sun turari, tí wọ́n sì ń rúbọ sí àwọn oriṣa wọn.

Àwọn Ọba Kinni 11

Àwọn Ọba Kinni 11:1-15