Àwọn Ọba Kinni 11:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní ìwọ Jeroboamu ni òun óo mú, tí òun óo sì fi jọba ní Israẹli, o óo sì máa jọba lórí gbogbo agbègbè tí ó bá wù ọ́.

Àwọn Ọba Kinni 11

Àwọn Ọba Kinni 11:28-39