Àwọn Ọba Kinni 11:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Òun óo fi ẹ̀yà kan sílẹ̀ fún ọmọ rẹ̀, kí ọ̀kan ninu arọmọdọmọ Dafidi, iranṣẹ òun, lè máa jọba nígbà gbogbo ní Jerusalẹmu, ìlú tí òun ti yàn fún ìjọ́sìn ní orúkọ òun.

Àwọn Ọba Kinni 11

Àwọn Ọba Kinni 11:35-43