Àwọn Ọba Kinni 11:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kan, Jeroboamu ń ti Jerusalẹmu lọ sí ìrìn àjò kan, wolii Ahija, láti Ṣilo sì pàdé òun nìkan lójú ọ̀nà, ninu pápá.

Àwọn Ọba Kinni 11

Àwọn Ọba Kinni 11:21-35