Àwọn Ọba Kinni 11:28 BIBELI MIMỌ (BM)

ó ṣe akiyesi Jeroboamu pé ó jẹ́ ọdọmọkunrin tí ó ní akitiyan. Nígbà tí Solomoni rí i bí ó ti ń ṣiṣẹ́ kára kára, ó fi ṣe olórí àwọn tí wọn ń kóni ṣiṣẹ́ tipátipá ní gbogbo agbègbè ẹ̀yà Manase ati Efuraimu.

Àwọn Ọba Kinni 11

Àwọn Ọba Kinni 11:21-32