Àwọn Ọba Kinni 11:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnìkan tí ó tún kẹ̀yìn sí Solomoni ni ọ̀kan ninu àwọn òṣìṣẹ́ rẹ̀ tí ń jẹ́ Jeroboamu, ọmọ Nebati, ará Sereda, ninu ẹ̀yà Efuraimu, obinrin opó kan tí ń jẹ́ Serua ni ìyá rẹ̀.

Àwọn Ọba Kinni 11

Àwọn Ọba Kinni 11:22-33