Àwọn Ọba Kinni 11:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀tá gidi ni ó jẹ́ fún Israẹli ní ìgbà ayé Solomoni, ó sì ṣe jamba bí Hadadi ti ṣe. Ó kórìíra àwọn ọmọ Israẹli, òun sì ni ọba ilẹ̀ Siria.

Àwọn Ọba Kinni 11

Àwọn Ọba Kinni 11:23-30