Àwọn Ọba Kinni 11:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun tún mú kí Resoni ọmọ Eliada dojú ọ̀tá kọ Solomoni, sísá ni Resoni yìí sá kúrò lọ́dọ̀ Hadadeseri, ọba Soba, tí ó jẹ́ ọ̀gá rẹ̀.

Àwọn Ọba Kinni 11

Àwọn Ọba Kinni 11:22-29