Àwọn Ọba Kinni 11:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Farao bá bi í léèrè pé, “Kí lo fẹ́ tí o kò rí lọ́dọ̀ mi, tí o fi fẹ́ máa lọ sí ìlú rẹ?”Ṣugbọn Adadi dá a lóhùn pé, “Ṣá jẹ́ kí n máa lọ.”

Àwọn Ọba Kinni 11

Àwọn Ọba Kinni 11:21-31