Àwọn Ọba Kinni 11:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Arabinrin ayaba Tapenesi yìí bí ọmọkunrin kan fún Adadi, ó sọ orúkọ rẹ̀ ní Genubati. Inú ilé Farao ọba ni ayaba Tapenesi ti tọ́ ọmọ náà dàgbà, láàrin àwọn ọmọ ọba.

Àwọn Ọba Kinni 11

Àwọn Ọba Kinni 11:17-24