Àwọn Ọba Kinni 11:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Adadi bá ojurere Farao ọba pàdé, ọba bá fi arabinrin ayaba Tapenesi, iyawo rẹ̀, fún Adadi kí ó fi ṣe aya.

Àwọn Ọba Kinni 11

Àwọn Ọba Kinni 11:11-21