Àwọn Ọba Kinni 1:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Adonija lọ jíròrò pẹlu Joabu, ọmọ Seruaya, ati Abiatari alufaa, àwọn mejeeji tẹ̀lé ọ̀rọ̀ rẹ̀, wọ́n sì ràn án lọ́wọ́.

Àwọn Ọba Kinni 1

Àwọn Ọba Kinni 1:1-16