Àwọn Ọba Kinni 1:34 BIBELI MIMỌ (BM)

kí Sadoku, alufaa ati Natani wolii, fi àmì òróró yàn án ní ọba níbẹ̀, lórí gbogbo Israẹli. Lẹ́yìn náà, kí ẹ fọn fèrè, kí ẹ sì hó pé, ‘Kí ẹ̀mí Solomoni, ọba, kí ó gùn!’

Àwọn Ọba Kinni 1

Àwọn Ọba Kinni 1:28-43