Àwọn Ọba Kinni 1:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba bá pàṣẹ fún wọn pé, “Ẹ kó gbogbo àwọn òṣìṣẹ́ mi lẹ́yìn, kí ẹ sì gbé Solomoni gun ìbaaka mi, kí ẹ mú un lọ sí odò Gihoni,

Àwọn Ọba Kinni 1

Àwọn Ọba Kinni 1:32-38