Àwọn Ọba Kinni 1:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Batiṣeba wólẹ̀ níwájú ọba, ó sì kí i tọ̀wọ̀tọ̀wọ̀. Ọba bá bi í pé, “Kí ni o fẹ́ gbà?”

Àwọn Ọba Kinni 1

Àwọn Ọba Kinni 1:15-25