Àwọn Ọba Kinni 1:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Batiṣeba bá wọlé tọ ọba lọ ninu yàrá rẹ̀. (Ọba ti di arúgbó ní àkókò yìí, Abiṣagi ará Ṣunemu ni ó ń tọ́jú rẹ̀.)

Àwọn Ọba Kinni 1

Àwọn Ọba Kinni 1:12-25