Àwọn Ọba Keji 9:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ìdílé Ahabu ni yóo ṣègbé, n óo sì pa gbogbo àwọn ọmọkunrin tí wọ́n wà ninu ìdílé náà, ati ẹrú ati ọmọ.

Àwọn Ọba Keji 9

Àwọn Ọba Keji 9:1-12