Àwọn Ọba Keji 9:7 BIBELI MIMỌ (BM)

O óo pa ìdílé oluwa rẹ, Ahabu ọba rẹ́, kí n lè gbẹ̀san lára Jesebẹli fún àwọn wolii mi ati àwọn iranṣẹ mi tí ó pa.

Àwọn Ọba Keji 9

Àwọn Ọba Keji 9:6-14