Àwọn Ọba Keji 8:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Obinrin náà gbọ́ ọ̀rọ̀ Eliṣa, òun ati ẹbí rẹ̀ sì lọ ń gbé ilẹ̀ àwọn ará Filistia fún ọdún meje.

Àwọn Ọba Keji 8

Àwọn Ọba Keji 8:1-3