Àwọn Ọba Keji 8:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Eliṣa sọ fún obinrin ará Ṣunemu, ẹni tí Eliṣa jí ọmọ rẹ̀ tí ó kú pé, “OLUWA yóo rán ìyàn sí ilẹ̀ yìí fún ọdún meje, nítorí náà, kí ìwọ ati ẹbí rẹ lọ máa gbé ní ilẹ̀ mìíràn.”

Àwọn Ọba Keji 8

Àwọn Ọba Keji 8:1-6