Àwọn Ọba Keji 5:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kan, ọmọbinrin náà sọ fún ọ̀gá rẹ̀ pé, “Bí oluwa mi Naamani bá lọ sí ọ̀dọ̀ wolii tí ó wà ní Samaria, yóo rí ìwòsàn gbà.”

Àwọn Ọba Keji 5

Àwọn Ọba Keji 5:1-5