Àwọn Ọba Keji 5:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Iyawo Naamani ní iranṣẹbinrin kékeré kan tí àwọn ará Siria mú lẹ́rú wá láti ilẹ̀ Israẹli, nígbà tí wọ́n lọ bá wọn jagun.

Àwọn Ọba Keji 5

Àwọn Ọba Keji 5:1-11