Àwọn Ọba Keji 4:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kan Eliṣa lọ sí Ṣunemu, níbi tí obinrin ọlọ́rọ̀ kan ń gbé; obinrin náà sì pe Eliṣa wọlé kí ó wá jẹun. Láti ìgbà náà, ilé obinrin yìí ni Eliṣa ti máa ń jẹun ní Ṣunemu.

Àwọn Ọba Keji 4

Àwọn Ọba Keji 4:6-15