Àwọn Ọba Keji 4:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá pada lọ sọ ohun tí ó ṣẹlẹ̀ fún wolii Eliṣa. Eliṣa wí fún un pé, “Lọ ta àwọn òróró náà kí o sì san gbèsè rẹ ninu rẹ̀, kí ìwọ ati àwọn ọmọ rẹ máa ná ìyókù.”

Àwọn Ọba Keji 4

Àwọn Ọba Keji 4:4-15