Àwọn Ọba Keji 4:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Sáré lọ pàdé rẹ̀ kí o sì bèèrè alaafia rẹ̀ ati ti ọkọ rẹ̀ ati ti ọmọ rẹ̀ pẹlu.”Obinrin náà dá Gehasi lóhùn pé, “Alaafia ni gbogbo wa wà.”

Àwọn Ọba Keji 4

Àwọn Ọba Keji 4:16-36