Àwọn Ọba Keji 4:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó lọ bá Eliṣa ní orí òkè Kamẹli.Eliṣa rí i tí ó ń bọ̀ lókèèrè, ó bá sọ fún Gehasi, iranṣẹ rẹ̀, pé, “Wò ó! Obinrin ará Ṣunemu nì ni ó ń bọ̀ yìí!

Àwọn Ọba Keji 4

Àwọn Ọba Keji 4:23-34