Àwọn Ọba Keji 25:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Nebukadinesari ọba Babiloni yan Gedalaya ọmọ Ahikamu, ọmọ Ṣafani ní gomina lórí àwọn tí wọ́n kù ní ilẹ̀ Juda.

Àwọn Ọba Keji 25

Àwọn Ọba Keji 25:20-24