Àwọn Ọba Keji 25:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba Babiloni lù wọ́n, ó sì pa wọ́n sórí ilẹ̀ Hamati.Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n sì ṣe kó Juda ní ìgbèkùn kúrò lórí ilẹ̀ rẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 25

Àwọn Ọba Keji 25:17-27