Àwọn Ọba Keji 24:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni ọdún mejidinlogun ni Jehoiakini nígbà tí ó jọba, ó sì wà lórí oyè ní Jerusalẹmu fún oṣù mẹta. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Nehuṣita, ọmọ Elinatani ará Jerusalẹmu.

Àwọn Ọba Keji 24

Àwọn Ọba Keji 24:4-11