Àwọn Ọba Keji 24:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba Ijipti kò lè jáde kúrò ní ilẹ̀ rẹ̀ mọ́, nítorí pé ọba Babiloni ti gba gbogbo ilẹ̀ ọba Ijipti láti odò Ijipti títí dé odò Yufurate.

Àwọn Ọba Keji 24

Àwọn Ọba Keji 24:2-16