Àwọn Ọba Keji 24:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba Babiloni kó ẹẹdẹgbaarin (7,000) àwọn akọni ní ìgbèkùn ati ẹgbẹrun kan (1,000) àwọn oníṣẹ́ ọwọ́ ati alágbẹ̀dẹ, gbogbo wọn jẹ́ alágbára tí wọ́n lè jagun.

Àwọn Ọba Keji 24

Àwọn Ọba Keji 24:8-20