Àwọn Ọba Keji 24:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kó ọba Jehoiakini, ati ìyá rẹ̀, ati àwọn aya rẹ̀, àwọn ìwẹ̀fà rẹ̀ ati àwọn ìjòyè ilẹ̀ náà ní ìgbèkùn láti Jerusalẹmu lọ sí Babiloni.

Àwọn Ọba Keji 24

Àwọn Ọba Keji 24:8-16