Àwọn Ọba Keji 23:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn sibẹsibẹ ibinu gbígbóná OLUWA tí ó ti ru sókè sí Juda nítorí ìwà burúkú Manase kò rọlẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 23

Àwọn Ọba Keji 23:18-30