Àwọn Ọba Keji 23:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣáájú Josaya ati lẹ́yìn rẹ̀, kò sí ọba kankan tí ó fi gbogbo ọkàn rẹ̀, gbogbo ẹ̀mí rẹ̀ ati gbogbo agbára rẹ̀ sin Ọlọrun, gẹ́gẹ́ bí ó ti wà ninu gbogbo òfin Mose.

Àwọn Ọba Keji 23

Àwọn Ọba Keji 23:22-27