Àwọn Ọba Keji 21:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé wọ́n ti ṣe ohun burúkú lójú òun, wọ́n sì ti mú òun bínú láti ìgbà tí àwọn baba ńlá wọn ti kúrò ní Ijipti, àní títí di òní olónìí.”

Àwọn Ọba Keji 21

Àwọn Ọba Keji 21:7-18