Àwọn Ọba Keji 21:14 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní òun óo kọ àwọn eniyan òun yòókù sílẹ̀, òun óo fi wọ́n lé àwọn ọ̀tá wọn lọ́wọ́, ọ̀tá yóo ṣẹgun wọn, wọn yóo sì kó wọn lọ bí ìkógun.

Àwọn Ọba Keji 21

Àwọn Ọba Keji 21:7-17