Àwọn Ọba Keji 19:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní alẹ́ ọjọ́ náà ni angẹli OLUWA lọ sí ibùdó ogun Asiria, ó sì pa ọ̀kẹ́ mẹsan-an lé ẹẹdẹgbaata (185,000) àwọn ọmọ ogun, wọn kú kí ilẹ̀ ọjọ́ keji tó mọ́.

Àwọn Ọba Keji 19

Àwọn Ọba Keji 19:29-37