Àwọn Ọba Keji 19:34 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo gbèjà ìlú yìí, n óo sì dáàbò bò ọ́ nítorí ògo mi ati ìlérí tí mo ti ṣe fún Dafidi iranṣẹ mi.”

Àwọn Ọba Keji 19

Àwọn Ọba Keji 19:25-36