Àwọn Ọba Keji 19:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan yóo là ní Jerusalẹmu, àwọn eniyan yóo sì ṣẹ́kù ni Òkè Sioni, nítorí pé ìtara ni OLUWA yóo fi ṣe é.

Àwọn Ọba Keji 19

Àwọn Ọba Keji 19:24-36